encantamiento de brujas de osa meyi

Upload: giraldo-legra

Post on 03-Jun-2018

235 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

  • 8/12/2019 Encantamiento de Brujas de Osa Meyi

    1/2

    Encantamiento de brujas de osa meyi

    Isan sa meyi otona gegere wolu Adifafun

    oshanla ti awon eleyenlee bowa ti wonnpe igba

    opolopo ahemi Adifafun Orunmila ti ogabada

    lowo orisati ofi ghaalale owo awo eleye ifa

    dakunwa gba eneia omore kal lowo gbogbo

    ajogun

    Encantamiento de oshe-tura

    Akakanika akakanika alakakanika alapasapaijakalu

    Eye kan fo feerete o wole akakanika li aa pe ifa

    alakakanika li aape odu alapasapa ijakaluli aape

    esu odara eye kan feerete o wole li aape aje

    omo Olokun sande oba olubu omi ogo owoni

    esu odara iwo liote ilu yi do iwo nikiijeki obikiopa alawo ilu iwo nikiijeki ebi kiopa unisegun

    ilu iwo nikiijwkiwbi kiopa adahuense ilu emi

    alawo ilu yi ree

    Emi unisegun ilu yi ree

    Emi adahunse ilu yi ree

  • 8/12/2019 Encantamiento de Brujas de Osa Meyi

    2/2

    Esu odara majek ebi pa mi ati beebee ewe ita

    naa: ewe abamoda kan ebu cerupe agbede aro,

    efun ati osun ao te odu osetura lori erupe

    agbede tiabuwale, ao sa igede tiwa luke y I bi a

    ti pee sibiyi sori erupe ebu inaa kiadadd pomo

    efun li owo otun lati fi te odu ose

    Kiadaapomo osun li owo osi pelu erupe naa lati

    kote odu otura si ara ewe abamoda naa kiopa

    obi alawe merin tiodara fun ifa yi owo dudu atifunfun niki a papo ku soor soke ninu ile eyo

    ataare meje ati awe Obi kan niki a maaje fin

    fun un nibiti a sooro s! ao maa fisa igede naa

    biatipee nibiyi lojo ojumo